March 29, 2023

A ṣe ìrìn-àjò lọ sí ilé ìtura Tana Suites ní ìlú Ògbómọ̀ṣọ́ láti bá ẹ̀gbọ́n Bàbá Olúgbénga Owólabí tó ni ilé ìtura náà lẹ́nu wò lẹ́yìn tí àwọn agbénigbowó ṣekú pa á àti àwọn méjì mìíràn lẹ́yìn tí wọ́n gba mílíọ̀nù márùn-ún náírà gẹ́gẹ́ bí owó ìdásílẹ.

Read More

Leave a Reply